Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qasas ayat 33 - القَصَص - Page - Juz 20
﴿قَالَ رَبِّ إِنِّي قَتَلۡتُ مِنۡهُمۡ نَفۡسٗا فَأَخَافُ أَن يَقۡتُلُونِ ﴾
[القَصَص: 33]
﴿قال رب إني قتلت منهم نفسا فأخاف أن يقتلون﴾ [القَصَص: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì Mūsā) sọ pé: “Olúwa mi, dájúdájú èmi pa ẹnì kan nínú wọn. Nítorí náà, mò ń bẹ̀rù pé wọ́n máa pa mí |