×

Ati pe A fi egun topa won ni ile aye yii. Ni 28:42 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Qasas ⮕ (28:42) ayat 42 in Yoruba

28:42 Surah Al-Qasas ayat 42 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qasas ayat 42 - القَصَص - Page - Juz 20

﴿وَأَتۡبَعۡنَٰهُمۡ فِي هَٰذِهِ ٱلدُّنۡيَا لَعۡنَةٗۖ وَيَوۡمَ ٱلۡقِيَٰمَةِ هُم مِّنَ ٱلۡمَقۡبُوحِينَ ﴾
[القَصَص: 42]

Ati pe A fi egun topa won ni ile aye yii. Ni Ojo Ajinde, won yo si wa ninu awon eni iparun

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وأتبعناهم في هذه الدنيا لعنة ويوم القيامة هم من المقبوحين, باللغة اليوربا

﴿وأتبعناهم في هذه الدنيا لعنة ويوم القيامة هم من المقبوحين﴾ [القَصَص: 42]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àti pé A fi ègún tọpa wọn ní ilé ayé yìí. Ní Ọjọ́ Àjíǹde, wọn yó sì wà nínú àwọn ẹni ìparun
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek