×

Dajudaju A ti fun (Anabi) Musa ni Tira leyin igba ti A 28:43 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Qasas ⮕ (28:43) ayat 43 in Yoruba

28:43 Surah Al-Qasas ayat 43 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qasas ayat 43 - القَصَص - Page - Juz 20

﴿وَلَقَدۡ ءَاتَيۡنَا مُوسَى ٱلۡكِتَٰبَ مِنۢ بَعۡدِ مَآ أَهۡلَكۡنَا ٱلۡقُرُونَ ٱلۡأُولَىٰ بَصَآئِرَ لِلنَّاسِ وَهُدٗى وَرَحۡمَةٗ لَّعَلَّهُمۡ يَتَذَكَّرُونَ ﴾
[القَصَص: 43]

Dajudaju A ti fun (Anabi) Musa ni Tira leyin igba ti A ti pa awon ijo akoko re. (Tira naa je) ariwoye fun awon eniyan, imona ati ike nitori ki won le lo iranti

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ولقد آتينا موسى الكتاب من بعد ما أهلكنا القرون الأولى بصائر للناس, باللغة اليوربا

﴿ولقد آتينا موسى الكتاب من بعد ما أهلكنا القرون الأولى بصائر للناس﴾ [القَصَص: 43]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú A ti fún (Ànábì) Mūsā ní Tírà lẹ́yìn ìgbà tí A ti pa àwọn ìjọ àkọ́kọ́ rẹ́. (Tírà náà jẹ́) àríwòye fún àwọn ènìyàn, ìmọ̀nà àti ìkẹ́ nítorí kí wọ́n lè lo ìrántí
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek