Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 34 - العَنكبُوت - Page - Juz 20
﴿إِنَّا مُنزِلُونَ عَلَىٰٓ أَهۡلِ هَٰذِهِ ٱلۡقَرۡيَةِ رِجۡزٗا مِّنَ ٱلسَّمَآءِ بِمَا كَانُواْ يَفۡسُقُونَ ﴾
[العَنكبُوت: 34]
﴿إنا منـزلون على أهل هذه القرية رجزا من السماء بما كانوا يفسقون﴾ [العَنكبُوت: 34]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú a máa sọ ìyà kan kalẹ̀ lé àwọn ará ìlú yìí lórí láti inú sánmọ̀ nítorí pé wọ́n jẹ́ òbìlẹ̀jẹ́ |