Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 35 - العَنكبُوت - Page - Juz 20
﴿وَلَقَد تَّرَكۡنَا مِنۡهَآ ءَايَةَۢ بَيِّنَةٗ لِّقَوۡمٖ يَعۡقِلُونَ ﴾
[العَنكبُوت: 35]
﴿ولقد تركنا منها آية بينة لقوم يعقلون﴾ [العَنكبُوت: 35]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A ti fi àmì kan t’ó fojú hàn lélẹ̀ nínú rẹ̀ fún ìjọ t’ó ní làákàyè |