Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 56 - العَنكبُوت - Page - Juz 21
﴿يَٰعِبَادِيَ ٱلَّذِينَ ءَامَنُوٓاْ إِنَّ أَرۡضِي وَٰسِعَةٞ فَإِيَّٰيَ فَٱعۡبُدُونِ ﴾
[العَنكبُوت: 56]
﴿ياعبادي الذين آمنوا إن أرضي واسعة فإياي فاعبدون﴾ [العَنكبُوت: 56]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀yin ẹrúsìn Mi, tí ẹ gbàgbọ́ ní òdodo, dájúdájú ilẹ̀ Mi gbòòrò. Nítorí náà, Èmi nìkan ni kí ẹ jọ́sìn fún |