Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 57 - العَنكبُوت - Page - Juz 21
﴿كُلُّ نَفۡسٖ ذَآئِقَةُ ٱلۡمَوۡتِۖ ثُمَّ إِلَيۡنَا تُرۡجَعُونَ ﴾
[العَنكبُوت: 57]
﴿كل نفس ذائقة الموت ثم إلينا ترجعون﴾ [العَنكبُوت: 57]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Gbogbo ẹ̀mí l’ó máa tọ́ ikú wò. Lẹ́yìn náà, ọ̀dọ̀ Wa ni wọn yóò da yín padà sí |