Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 9 - العَنكبُوت - Page - Juz 20
﴿وَٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَمِلُواْ ٱلصَّٰلِحَٰتِ لَنُدۡخِلَنَّهُمۡ فِي ٱلصَّٰلِحِينَ ﴾
[العَنكبُوت: 9]
﴿والذين آمنوا وعملوا الصالحات لندخلنهم في الصالحين﴾ [العَنكبُوت: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn t’ó bá gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n sì ṣe iṣẹ́ rere, dájúdájú A máa fi wọ́n sínú àwọn ẹni rere |