×

Ko letoo fun emi kan lati ku afi pelu iyonda Allahu. (Iku 3:145 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah al-‘Imran ⮕ (3:145) ayat 145 in Yoruba

3:145 Surah al-‘Imran ayat 145 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 145 - آل عِمران - Page - Juz 4

﴿وَمَا كَانَ لِنَفۡسٍ أَن تَمُوتَ إِلَّا بِإِذۡنِ ٱللَّهِ كِتَٰبٗا مُّؤَجَّلٗاۗ وَمَن يُرِدۡ ثَوَابَ ٱلدُّنۡيَا نُؤۡتِهِۦ مِنۡهَا وَمَن يُرِدۡ ثَوَابَ ٱلۡأٓخِرَةِ نُؤۡتِهِۦ مِنۡهَاۚ وَسَنَجۡزِي ٱلشَّٰكِرِينَ ﴾
[آل عِمران: 145]

Ko letoo fun emi kan lati ku afi pelu iyonda Allahu. (Iku je) akosile onigbedeke. Enikeni ti o ba n fe esan (ni) aye, A maa fun un ni aye. Enikeni ti o ba si n fe esan (ni) orun, A maa fun un ni orun. A o si san awon oludupe ni esan rere

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وما كان لنفس أن تموت إلا بإذن الله كتابا مؤجلا ومن يرد, باللغة اليوربا

﴿وما كان لنفس أن تموت إلا بإذن الله كتابا مؤجلا ومن يرد﴾ [آل عِمران: 145]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Kò lẹ́tọ̀ọ́ fún ẹ̀mí kan láti kú àfi pẹ̀lú ìyọ̀ǹda Allāhu. (Ikú jẹ́) àkọsílẹ̀ onígbèdéke. Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń fẹ́ ẹ̀san (ní) ayé, A máa fún un ní ayé. Ẹnikẹ́ni tí ó bá sì ń fẹ́ ẹ̀san (ní) ọ̀run, A máa fún un ní ọ̀run. A ó sì san àwọn olùdúpẹ́ ní ẹ̀san rere
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek