×

Dajudaju ti e ba ku (sinu ile) tabi won pa yin (s’oju 3:158 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah al-‘Imran ⮕ (3:158) ayat 158 in Yoruba

3:158 Surah al-‘Imran ayat 158 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 158 - آل عِمران - Page - Juz 4

﴿وَلَئِن مُّتُّمۡ أَوۡ قُتِلۡتُمۡ لَإِلَى ٱللَّهِ تُحۡشَرُونَ ﴾
[آل عِمران: 158]

Dajudaju ti e ba ku (sinu ile) tabi won pa yin (s’oju ogun esin), dajudaju odo Allahu ni won maa ko yin jo si

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ولئن متم أو قتلتم لإلى الله تحشرون, باللغة اليوربا

﴿ولئن متم أو قتلتم لإلى الله تحشرون﴾ [آل عِمران: 158]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú tí ẹ bá kú (sínú ilé) tàbí wọ́n pa yín (s’ójú ogun ẹ̀sìn), dájúdájú ọ̀dọ̀ Allāhu ni wọn máa ko yín jọ sí
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek