×

Awon t’o so nipa awon omo iya won (t’o ku s’oju ogun 3:168 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah al-‘Imran ⮕ (3:168) ayat 168 in Yoruba

3:168 Surah al-‘Imran ayat 168 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 168 - آل عِمران - Page - Juz 4

﴿ٱلَّذِينَ قَالُواْ لِإِخۡوَٰنِهِمۡ وَقَعَدُواْ لَوۡ أَطَاعُونَا مَا قُتِلُواْۗ قُلۡ فَٱدۡرَءُواْ عَنۡ أَنفُسِكُمُ ٱلۡمَوۡتَ إِن كُنتُمۡ صَٰدِقِينَ ﴾
[آل عِمران: 168]

Awon t’o so nipa awon omo iya won (t’o ku s’oju ogun esin) pe – ti awon si jokoo kale sile (ni tiwon), "Ti o ba je pe won tele tiwa ni, won iba ti pa won." So pe: “E yeku danu fun emi yin ti e ba je olododo.”

❮ Previous Next ❯

ترجمة: الذين قالوا لإخوانهم وقعدوا لو أطاعونا ما قتلوا قل فادرءوا عن أنفسكم, باللغة اليوربا

﴿الذين قالوا لإخوانهم وقعدوا لو أطاعونا ما قتلوا قل فادرءوا عن أنفسكم﴾ [آل عِمران: 168]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn t’ó sọ nípa àwọn ọmọ ìyá wọn (t’ó kú s’ójú ogun ẹ̀sìn) pé – tí àwọn sì jòkóò kalẹ̀ sílé (ní tiwọn), "Tí ó bá jẹ́ pé wọ́n tẹ̀lé tiwa ni, wọn ìbá tí pa wọ́n." Sọ pé: “Ẹ yẹkú dànù fún ẹ̀mí yín tí ẹ bá jẹ́ olódodo.”
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek