Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 34 - آل عِمران - Page - Juz 3
﴿ذُرِّيَّةَۢ بَعۡضُهَا مِنۢ بَعۡضٖۗ وَٱللَّهُ سَمِيعٌ عَلِيمٌ ﴾
[آل عِمران: 34]
﴿ذرية بعضها من بعض والله سميع عليم﴾ [آل عِمران: 34]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n jẹ́ àrọ́mọdọ́mọ; apá kan wọn wá láti ara apá kan. Allāhu sì ni Olùgbọ́, Onímọ̀ |