Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 46 - آل عِمران - Page - Juz 3
﴿وَيُكَلِّمُ ٱلنَّاسَ فِي ٱلۡمَهۡدِ وَكَهۡلٗا وَمِنَ ٱلصَّٰلِحِينَ ﴾
[آل عِمران: 46]
﴿ويكلم الناس في المهد وكهلا ومن الصالحين﴾ [آل عِمران: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó máa bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ lórí ìtẹ́ ní òpóǹló àti nígbà t’ó bá dàgbà. Ó sì wà nínú àwọn ẹni rere |