Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 82 - آل عِمران - Page - Juz 3
﴿فَمَن تَوَلَّىٰ بَعۡدَ ذَٰلِكَ فَأُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡفَٰسِقُونَ ﴾
[آل عِمران: 82]
﴿فمن تولى بعد ذلك فأولئك هم الفاسقون﴾ [آل عِمران: 82]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ẹni tí ó bá kẹ̀yìn sí (Ànábì Muhammad s.a.w.) lẹ́yìn (àdéhùn) yẹn, àwọn wọ̀nyẹn ni òbìlẹ̀jẹ́ |