Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rum ayat 14 - الرُّوم - Page - Juz 21
﴿وَيَوۡمَ تَقُومُ ٱلسَّاعَةُ يَوۡمَئِذٖ يَتَفَرَّقُونَ ﴾
[الرُّوم: 14]
﴿ويوم تقوم الساعة يومئذ يتفرقون﴾ [الرُّوم: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ọjọ́ tí Àkókò náà máa ṣẹlẹ̀, ní ọjọ́ yẹn ni wọn yóò pínyà sí ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ |