Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rum ayat 13 - الرُّوم - Page - Juz 21
﴿وَلَمۡ يَكُن لَّهُم مِّن شُرَكَآئِهِمۡ شُفَعَٰٓؤُاْ وَكَانُواْ بِشُرَكَآئِهِمۡ كَٰفِرِينَ ﴾
[الرُّوم: 13]
﴿ولم يكن لهم من شركائهم شفعاء وكانوا بشركائهم كافرين﴾ [الرُّوم: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé kò níí sí àwọn olùṣìpẹ̀ fún wọn nínú àwọn òrìṣà wọn. Wọ́n sì máa jẹ́ alátakò òrìṣà wọn |