Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rum ayat 15 - الرُّوم - Page - Juz 21
﴿فَأَمَّا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَمِلُواْ ٱلصَّٰلِحَٰتِ فَهُمۡ فِي رَوۡضَةٖ يُحۡبَرُونَ ﴾
[الرُّوم: 15]
﴿فأما الذين آمنوا وعملوا الصالحات فهم في روضة يحبرون﴾ [الرُّوم: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n sì ṣe iṣẹ́ rere, wọn yóò wà ní àyè t’ó rẹwà jùlọ nínú Ọgbà Ìdẹ̀ra, tí wọn yó sì máa dunnú |