Quran with Yoruba translation - Surah Luqman ayat 18 - لُقمَان - Page - Juz 21
﴿وَلَا تُصَعِّرۡ خَدَّكَ لِلنَّاسِ وَلَا تَمۡشِ فِي ٱلۡأَرۡضِ مَرَحًاۖ إِنَّ ٱللَّهَ لَا يُحِبُّ كُلَّ مُخۡتَالٖ فَخُورٖ ﴾
[لُقمَان: 18]
﴿ولا تصعر خدك للناس ولا تمش في الأرض مرحا إن الله لا﴾ [لُقمَان: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Má ṣe kọ párìkẹ́ rẹ sí ènìyàn. Má sì ṣe rìn lórí ilẹ̀ pẹ̀lú fáàrí. Dájúdájú Allāhu kò fẹ́ràn gbogbo onígbèéraga, onífáàrí |