Quran with Yoruba translation - Surah Luqman ayat 8 - لُقمَان - Page - Juz 21
﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَمِلُواْ ٱلصَّٰلِحَٰتِ لَهُمۡ جَنَّٰتُ ٱلنَّعِيمِ ﴾
[لُقمَان: 8]
﴿إن الذين آمنوا وعملوا الصالحات لهم جنات النعيم﴾ [لُقمَان: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n sì ṣe iṣẹ́ rere, àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra ń bẹ fún wọn |