Quran with Yoruba translation - Surah As-Sajdah ayat 30 - السَّجدة - Page - Juz 21
﴿فَأَعۡرِضۡ عَنۡهُمۡ وَٱنتَظِرۡ إِنَّهُم مُّنتَظِرُونَ ﴾
[السَّجدة: 30]
﴿فأعرض عنهم وانتظر إنهم منتظرون﴾ [السَّجدة: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ṣẹ́rí kúrò lọ́dọ̀ wọn, kí o sì máa retí (Ọjọ́ Ìdájọ́). Dájúdájú àwọn náà ń retí (rẹ̀) |