Quran with Yoruba translation - Surah As-Sajdah ayat 6 - السَّجدة - Page - Juz 21
﴿ذَٰلِكَ عَٰلِمُ ٱلۡغَيۡبِ وَٱلشَّهَٰدَةِ ٱلۡعَزِيزُ ٱلرَّحِيمُ ﴾
[السَّجدة: 6]
﴿ذلك عالم الغيب والشهادة العزيز الرحيم﴾ [السَّجدة: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn ni Onímọ̀-ìkọ̀kọ̀ àti gban̄gba, Alágbára, Àṣàkẹ́-ọ̀run |