Quran with Yoruba translation - Surah As-Sajdah ayat 7 - السَّجدة - Page - Juz 21
﴿ٱلَّذِيٓ أَحۡسَنَ كُلَّ شَيۡءٍ خَلَقَهُۥۖ وَبَدَأَ خَلۡقَ ٱلۡإِنسَٰنِ مِن طِينٖ ﴾
[السَّجدة: 7]
﴿الذي أحسن كل شيء خلقه وبدأ خلق الإنسان من طين﴾ [السَّجدة: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni t’ó ṣe gbogbo n̄ǹkan tí Ó dá ní dáadáa. Ó sì bẹ̀rẹ̀ ìṣẹ̀dá ènìyàn láti inú erùpẹ̀ amọ̀ |