Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ahzab ayat 11 - الأحزَاب - Page - Juz 21
﴿هُنَالِكَ ٱبۡتُلِيَ ٱلۡمُؤۡمِنُونَ وَزُلۡزِلُواْ زِلۡزَالٗا شَدِيدٗا ﴾
[الأحزَاب: 11]
﴿هنالك ابتلي المؤمنون وزلزلوا زلزالا شديدا﴾ [الأحزَاب: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Níbẹ̀ yẹn ni wọ́n ti fi àdánwò kan àwọn onígbàgbọ́ òdodo. Wọ́n sì milẹ̀ mọ́ wọn lẹ́sẹ̀ ní ìmìtìtì líle |