Quran with Yoruba translation - Surah Saba’ ayat 34 - سَبإ - Page - Juz 22
﴿وَمَآ أَرۡسَلۡنَا فِي قَرۡيَةٖ مِّن نَّذِيرٍ إِلَّا قَالَ مُتۡرَفُوهَآ إِنَّا بِمَآ أُرۡسِلۡتُم بِهِۦ كَٰفِرُونَ ﴾
[سَبإ: 34]
﴿وما أرسلنا في قرية من نذير إلا قال مترفوها إنا بما أرسلتم﴾ [سَبإ: 34]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé A ò rán olùkìlọ̀ kan sí ìlú kan àyàfi kí àwọn onígbẹdẹmukẹ ìlú náà wí pé: “Dájúdájú àwa ṣàì gbàgbọ́ nínú ohun tí Wọ́n fi ran yín níṣẹ́.” |