Quran with Yoruba translation - Surah Saba’ ayat 53 - سَبإ - Page - Juz 22
﴿وَقَدۡ كَفَرُواْ بِهِۦ مِن قَبۡلُۖ وَيَقۡذِفُونَ بِٱلۡغَيۡبِ مِن مَّكَانِۭ بَعِيدٖ ﴾
[سَبإ: 53]
﴿وقد كفروا به من قبل ويقذفون بالغيب من مكان بعيد﴾ [سَبإ: 53]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n kúkú ti ṣàì gbàgbọ́ nínú rẹ̀ ṣíwájú (nílé ayé). Wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ nípa ìkọ̀kọ̀ láti àyè t’ó jìnnà (ìyẹn, ilé ayé) |