Quran with Yoruba translation - Surah FaTir ayat 35 - فَاطِر - Page - Juz 22
﴿ٱلَّذِيٓ أَحَلَّنَا دَارَ ٱلۡمُقَامَةِ مِن فَضۡلِهِۦ لَا يَمَسُّنَا فِيهَا نَصَبٞ وَلَا يَمَسُّنَا فِيهَا لُغُوبٞ ﴾
[فَاطِر: 35]
﴿الذي أحلنا دار المقامة من فضله لا يمسنا فيها نصب ولا يمسنا﴾ [فَاطِر: 35]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni tí Ó sọ̀ wá kalẹ̀ sínú ibùgbé gbére nínú oore àjùlọ Rẹ̀. Wàhálà kan kò níí kàn wá nínú rẹ̀. Ìkáàárẹ̀ kan kò sì níí bá wa nínú rẹ̀ |