Quran with Yoruba translation - Surah FaTir ayat 6 - فَاطِر - Page - Juz 22
﴿إِنَّ ٱلشَّيۡطَٰنَ لَكُمۡ عَدُوّٞ فَٱتَّخِذُوهُ عَدُوًّاۚ إِنَّمَا يَدۡعُواْ حِزۡبَهُۥ لِيَكُونُواْ مِنۡ أَصۡحَٰبِ ٱلسَّعِيرِ ﴾
[فَاطِر: 6]
﴿إن الشيطان لكم عدو فاتخذوه عدوا إنما يدعو حزبه ليكونوا من أصحاب﴾ [فَاطِر: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Èṣù ni ọ̀tá fun yín. Nítorí náà, ẹ mú un ní ọ̀tá. Ó kàn ń pe àwọn ìjọ rẹ̀ nítorí kí wọ́n lè jẹ́ èrò inú Iná t’ó ń jò fòfò |