Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 16 - يسٓ - Page - Juz 22
﴿قَالُواْ رَبُّنَا يَعۡلَمُ إِنَّآ إِلَيۡكُمۡ لَمُرۡسَلُونَ ﴾
[يسٓ: 16]
﴿قالوا ربنا يعلم إنا إليكم لمرسلون﴾ [يسٓ: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: "Olúwa wa mọ̀ pé dájúdájú àwa ni Òjíṣẹ́ tí Wọ́n rán níṣẹ́ si yín |