Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 30 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿يَٰحَسۡرَةً عَلَى ٱلۡعِبَادِۚ مَا يَأۡتِيهِم مِّن رَّسُولٍ إِلَّا كَانُواْ بِهِۦ يَسۡتَهۡزِءُونَ ﴾
[يسٓ: 30]
﴿ياحسرة على العباد ما يأتيهم من رسول إلا كانوا به يستهزئون﴾ [يسٓ: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àbámọ̀ mà ni fún àwọn ẹrúsìn náà; òjíṣẹ́ kan kò níí wá bá wọn àyàfi kí wọ́n máa fi ṣe yẹ̀yẹ́ |