Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 32 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿وَإِن كُلّٞ لَّمَّا جَمِيعٞ لَّدَيۡنَا مُحۡضَرُونَ ﴾
[يسٓ: 32]
﴿وإن كل لما جميع لدينا محضرون﴾ [يسٓ: 32]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú gbogbo wọn pátápátá sì ni wọ́n máa kó wá sí ọ̀dọ̀ Wa |