Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 7 - يسٓ - Page - Juz 22
﴿لَقَدۡ حَقَّ ٱلۡقَوۡلُ عَلَىٰٓ أَكۡثَرِهِمۡ فَهُمۡ لَا يُؤۡمِنُونَ ﴾
[يسٓ: 7]
﴿لقد حق القول على أكثرهم فهم لا يؤمنون﴾ [يسٓ: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú ọ̀rọ̀ náà ti kò lé ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn lórí; wọn kò sì níí gbàgbọ́ |