Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 14 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿وَإِذَا رَأَوۡاْ ءَايَةٗ يَسۡتَسۡخِرُونَ ﴾
[الصَّافَات: 14]
﴿وإذا رأوا آية يستسخرون﴾ [الصَّافَات: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí wọ́n bá tún rí àmì kan, wọn yóò máa ṣe yẹ̀yẹ́ |