Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 15 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿وَقَالُوٓاْ إِنۡ هَٰذَآ إِلَّا سِحۡرٞ مُّبِينٌ ﴾
[الصَّافَات: 15]
﴿وقالوا إن هذا إلا سحر مبين﴾ [الصَّافَات: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sì wí pé: "Èyí kò jẹ́ kiní kan bí kò ṣe idán pọ́nńbélé |