Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 180 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿سُبۡحَٰنَ رَبِّكَ رَبِّ ٱلۡعِزَّةِ عَمَّا يَصِفُونَ ﴾
[الصَّافَات: 180]
﴿سبحان ربك رب العزة عما يصفون﴾ [الصَّافَات: 180]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Mímọ́ ni fún Olúwa rẹ, Olúwa agbára, tayọ ohun tí wọ́n ń fi ròyìn (Rẹ̀) |