Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 14 - صٓ - Page - Juz 23
﴿إِن كُلٌّ إِلَّا كَذَّبَ ٱلرُّسُلَ فَحَقَّ عِقَابِ ﴾
[صٓ: 14]
﴿إن كل إلا كذب الرسل فحق عقاب﴾ [صٓ: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sí ẹnì kan nínú wọn tí kò pe àwọn Òjíṣẹ́ ní òpùrọ́. Nítorí náà, ìyà Mi sì kò lé wọn lórí |