Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 16 - صٓ - Page - Juz 23
﴿وَقَالُواْ رَبَّنَا عَجِّل لَّنَا قِطَّنَا قَبۡلَ يَوۡمِ ٱلۡحِسَابِ ﴾
[صٓ: 16]
﴿وقالوا ربنا عجل لنا قطنا قبل يوم الحساب﴾ [صٓ: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: "Olúwa wa, yára fi ìwé iṣẹ́ wa (àti ẹ̀san wa) lé wa lọ́wọ́ ṣíwájú Ọjọ́ ìṣírò-iṣẹ́ |