Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 18 - صٓ - Page - Juz 23
﴿إِنَّا سَخَّرۡنَا ٱلۡجِبَالَ مَعَهُۥ يُسَبِّحۡنَ بِٱلۡعَشِيِّ وَٱلۡإِشۡرَاقِ ﴾
[صٓ: 18]
﴿إنا سخرنا الجبال معه يسبحن بالعشي والإشراق﴾ [صٓ: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa tẹ àwọn àpáta lórí ba tí wọ́n ń ṣe àfọ̀mọ́ pẹ̀lú rẹ̀ (fún Allāhu) ní àṣálẹ́ àti nígbà tí òòrùn bá yọ |