Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 36 - صٓ - Page - Juz 23
﴿فَسَخَّرۡنَا لَهُ ٱلرِّيحَ تَجۡرِي بِأَمۡرِهِۦ رُخَآءً حَيۡثُ أَصَابَ ﴾
[صٓ: 36]
﴿فسخرنا له الريح تجري بأمره رخاء حيث أصاب﴾ [صٓ: 36]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, A tẹ atẹ́gùn ba fún un. Ó ń fẹ́ pẹ̀lú àṣẹ rẹ̀ ní ìrọ̀rùn síbi tí ó bá fẹ́ |