Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 31 - الزُّمَر - Page - Juz 23
﴿ثُمَّ إِنَّكُمۡ يَوۡمَ ٱلۡقِيَٰمَةِ عِندَ رَبِّكُمۡ تَخۡتَصِمُونَ ﴾
[الزُّمَر: 31]
﴿ثم إنكم يوم القيامة عند ربكم تختصمون﴾ [الزُّمَر: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, ní Ọjọ́ Àjíǹde dájúdájú ẹ̀yin yóò máa bá ara yín ṣe àríyànjiyàn ní ọ̀dọ̀ Olúwa yín |