Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 121 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿أُوْلَٰٓئِكَ مَأۡوَىٰهُمۡ جَهَنَّمُ وَلَا يَجِدُونَ عَنۡهَا مَحِيصٗا ﴾
[النِّسَاء: 121]
﴿أولئك مأواهم جهنم ولا يجدون عنها محيصا﴾ [النِّسَاء: 121]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn wọ̀nyẹn, iná Jahanamọ ni ibùgbé wọn; wọn kò sì níí rí ibùsásí kan |