×

Ki i se ife-okan yin, bee ni ki i se ife-okan awon 4:123 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:123) ayat 123 in Yoruba

4:123 Surah An-Nisa’ ayat 123 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 123 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿لَّيۡسَ بِأَمَانِيِّكُمۡ وَلَآ أَمَانِيِّ أَهۡلِ ٱلۡكِتَٰبِۗ مَن يَعۡمَلۡ سُوٓءٗا يُجۡزَ بِهِۦ وَلَا يَجِدۡ لَهُۥ مِن دُونِ ٱللَّهِ وَلِيّٗا وَلَا نَصِيرٗا ﴾
[النِّسَاء: 123]

Ki i se ife-okan yin, bee ni ki i se ife-okan awon ahlu-l-kitab (ni osuwon idajo orun. Amo,) enikeni ti o ba sise aburu kan, A oo san an ni esan re; ko si nii ri alafeyinti tabi alaranse kan leyin Allahu

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ليس بأمانيكم ولا أماني أهل الكتاب من يعمل سوءا يجز به ولا, باللغة اليوربا

﴿ليس بأمانيكم ولا أماني أهل الكتاب من يعمل سوءا يجز به ولا﴾ [النِّسَاء: 123]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Kì í ṣe ìfẹ́-ọkàn yín, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe ìfẹ́-ọkàn àwọn ahlu-l-kitāb (ni òṣùwọ̀n ìdájọ́ ọ̀run. Àmọ́,) ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣiṣẹ́ aburú kan, A óò san án ní ẹ̀san rẹ̀; kò sì níí rí aláfẹ̀yìntì tàbí alárànṣe kan lẹ́yìn Allāhu
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek