×

(Awon ni) awon t’o fe yo yin; ti isegun kan lati odo 4:141 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:141) ayat 141 in Yoruba

4:141 Surah An-Nisa’ ayat 141 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 141 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿ٱلَّذِينَ يَتَرَبَّصُونَ بِكُمۡ فَإِن كَانَ لَكُمۡ فَتۡحٞ مِّنَ ٱللَّهِ قَالُوٓاْ أَلَمۡ نَكُن مَّعَكُمۡ وَإِن كَانَ لِلۡكَٰفِرِينَ نَصِيبٞ قَالُوٓاْ أَلَمۡ نَسۡتَحۡوِذۡ عَلَيۡكُمۡ وَنَمۡنَعۡكُم مِّنَ ٱلۡمُؤۡمِنِينَۚ فَٱللَّهُ يَحۡكُمُ بَيۡنَكُمۡ يَوۡمَ ٱلۡقِيَٰمَةِۚ وَلَن يَجۡعَلَ ٱللَّهُ لِلۡكَٰفِرِينَ عَلَى ٱلۡمُؤۡمِنِينَ سَبِيلًا ﴾
[النِّسَاء: 141]

(Awon ni) awon t’o fe yo yin; ti isegun kan lati odo Allahu ba je tiyin, won a wi pe: “Se awa ko wa pelu yin bi?” Ti ipin kan ba si wa fun awon alaigbagbo, (awon munaafiki) a wi pe: “Se awa ko ti ni ikapa lati je gaba le yin lori (amo ti awa ko se bee), se awa ko si daabo bo yin to lowo awon onigbagbo ododo (titi owo yin fi ba oro-ogun, nitori naa ki ni ipin tiwa ti e fe fun wa?)” Nitori naa, Allahu yoo sedajo laaarin yin ni Ojo Ajinde. Allahu ko si nii fun awon alaigbagbo ni ona (isegun) kan lori awon onigbagbo ododo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: الذين يتربصون بكم فإن كان لكم فتح من الله قالوا ألم نكن, باللغة اليوربا

﴿الذين يتربصون بكم فإن كان لكم فتح من الله قالوا ألم نكن﴾ [النِّسَاء: 141]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
(Àwọn ni) àwọn t’ó fẹ́ yọ̀ yín; tí ìṣẹ́gun kan láti ọ̀dọ̀ Allāhu bá jẹ́ tiyín, wọ́n á wí pé: “Ṣé àwa kò wà pẹ̀lú yín bí?” Tí ìpín kan bá sì wà fún àwọn aláìgbàgbọ́, (àwọn mùnááfìkí) á wí pé: “Ṣé àwa kò ti ní ìkápá láti jẹ gàba le yín lórí (àmọ́ tí àwa kò ṣe bẹ́ẹ̀), ṣé àwa kò sì dáàbò bò yín tó lọ́wọ́ àwọn onígbàgbọ́ òdodo (títí ọwọ́ yín fi ba ọrọ̀-ogun, nítorí náà kí ni ìpín tiwa tí ẹ fẹ́ fún wa?)” Nítorí náà, Allāhu yóò ṣèdájọ́ láààrin yín ní Ọjọ́ Àjíǹde. Allāhu kò sì níí fún àwọn aláìgbàgbọ́ ní ọ̀nà (ìṣẹ́gun) kan lórí àwọn onígbàgbọ́ òdodo
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek