×

A gbe apata soke ori won nitori majemu won. A si so 4:154 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:154) ayat 154 in Yoruba

4:154 Surah An-Nisa’ ayat 154 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 154 - النِّسَاء - Page - Juz 6

﴿وَرَفَعۡنَا فَوۡقَهُمُ ٱلطُّورَ بِمِيثَٰقِهِمۡ وَقُلۡنَا لَهُمُ ٱدۡخُلُواْ ٱلۡبَابَ سُجَّدٗا وَقُلۡنَا لَهُمۡ لَا تَعۡدُواْ فِي ٱلسَّبۡتِ وَأَخَذۡنَا مِنۡهُم مِّيثَٰقًا غَلِيظٗا ﴾
[النِّسَاء: 154]

A gbe apata soke ori won nitori majemu won. A si so fun won pe: “E gba enu-ona ilu wole ni oluteriba.” A tun so fun won pe: “E ma se tayo enu-ala ni ojo Sabt.” A si gba adehun t’o nipon lowo won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ورفعنا فوقهم الطور بميثاقهم وقلنا لهم ادخلوا الباب سجدا وقلنا لهم لا, باللغة اليوربا

﴿ورفعنا فوقهم الطور بميثاقهم وقلنا لهم ادخلوا الباب سجدا وقلنا لهم لا﴾ [النِّسَاء: 154]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
A gbé àpáta sókè orí wọn nítorí májẹ̀mu wọn. A sì sọ fún wọn pé: “Ẹ gba ẹnu-ọ̀nà ìlú wọlé ní olùtẹríba.” A tún sọ fún wọn pé: “Ẹ má ṣe tayọ ẹnu-àlà ní ọjọ́ Sabt.” A sì gba àdéhùn t’ó nípọn lọ́wọ́ wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek