Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 17 - النِّسَاء - Page - Juz 4
﴿إِنَّمَا ٱلتَّوۡبَةُ عَلَى ٱللَّهِ لِلَّذِينَ يَعۡمَلُونَ ٱلسُّوٓءَ بِجَهَٰلَةٖ ثُمَّ يَتُوبُونَ مِن قَرِيبٖ فَأُوْلَٰٓئِكَ يَتُوبُ ٱللَّهُ عَلَيۡهِمۡۗ وَكَانَ ٱللَّهُ عَلِيمًا حَكِيمٗا ﴾
[النِّسَاء: 17]
﴿إنما التوبة على الله للذين يعملون السوء بجهالة ثم يتوبون من قريب﴾ [النِّسَاء: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìronúpìwàdà tí Allāhu yóò gbà ni ti àwọn t’ó ń ṣe iṣẹ́ aburú pẹ̀lú àìmọ̀kan. Lẹ́yìn náà, wọ́n ronú pìwàdà láìpẹ́. Àwọn wọ̀nyí ni Allāhu yóò gba ìronúpìwàdà wọn. Allāhu sì ń jẹ́ Onímọ̀, Ọlọ́gbọ́n |