Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 27 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿وَقَالَ مُوسَىٰٓ إِنِّي عُذۡتُ بِرَبِّي وَرَبِّكُم مِّن كُلِّ مُتَكَبِّرٖ لَّا يُؤۡمِنُ بِيَوۡمِ ٱلۡحِسَابِ ﴾
[غَافِر: 27]
﴿وقال موسى إني عذت بربي وربكم من كل متكبر لا يؤمن بيوم﴾ [غَافِر: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì) Mūsā sọ pé: "Dájúdájú èmi sá di Olúwa mi àti Olúwa yín kúrò lọ́wọ́ gbogbo onígbèéraga, tí kò gba Ọjọ́ ìṣírò-iṣẹ́ gbọ́ |