Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 36 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿وَقَالَ فِرۡعَوۡنُ يَٰهَٰمَٰنُ ٱبۡنِ لِي صَرۡحٗا لَّعَلِّيٓ أَبۡلُغُ ٱلۡأَسۡبَٰبَ ﴾
[غَافِر: 36]
﴿وقال فرعون ياهامان ابن لي صرحا لعلي أبلغ الأسباب﴾ [غَافِر: 36]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Fir‘aon wí pé: "Hāmọ̄n, mọ ilé gíga fíofío kan fún mi nítorí kí èmi lè dé àwọn ojú ọ̀nà náà |