Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 41 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿۞ وَيَٰقَوۡمِ مَا لِيٓ أَدۡعُوكُمۡ إِلَى ٱلنَّجَوٰةِ وَتَدۡعُونَنِيٓ إِلَى ٱلنَّارِ ﴾
[غَافِر: 41]
﴿وياقوم ما لي أدعوكم إلى النجاة وتدعونني إلى النار﴾ [غَافِر: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀yin ènìyàn mi, kí ló mú yín tí mò ń pè yín síbi ìgbàlà, tí ẹ̀yin sì ń pè mí síbi Iná |