Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 48 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿قَالَ ٱلَّذِينَ ٱسۡتَكۡبَرُوٓاْ إِنَّا كُلّٞ فِيهَآ إِنَّ ٱللَّهَ قَدۡ حَكَمَ بَيۡنَ ٱلۡعِبَادِ ﴾
[غَافِر: 48]
﴿قال الذين استكبروا إنا كل فيها إن الله قد حكم بين العباد﴾ [غَافِر: 48]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn t’ó ṣègbéraga wí pé: "Dájúdájú gbogbo wa l’a wà nínú rẹ̀.” Dájúdájú Allāhu kúkú ti dájọ́ láààrin àwọn ẹrú náà |