Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 73 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿ثُمَّ قِيلَ لَهُمۡ أَيۡنَ مَا كُنتُمۡ تُشۡرِكُونَ ﴾
[غَافِر: 73]
﴿ثم قيل لهم أين ما كنتم تشركون﴾ [غَافِر: 73]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, Wọ́n máa sọ fún wọn pé: "Ibo ni ohun tí ẹ sọ di òrìṣà wà |