Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shura ayat 34 - الشُّوري - Page - Juz 25
﴿أَوۡ يُوبِقۡهُنَّ بِمَا كَسَبُواْ وَيَعۡفُ عَن كَثِيرٖ ﴾
[الشُّوري: 34]
﴿أو يوبقهن بما كسبوا ويعف عن كثير﴾ [الشُّوري: 34]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí Allāhu bá fẹ́, Ó máa mú atẹ́gùn náà dúró, (àwọn ọkọ̀ ojú-omi náà) sì máa di ohun tí kò níí lọ mọ́ lórí omi. Dájúdájú àwọn àmì wà nínú ìyẹn fún gbogbo onísùúrù, olùdúpẹ́ |